Ojo Kerin Osu Karun Odun  2016 E kaabo si ALAROYE.... iwe iroyin ti n soju omo Yoruba nibi gbogbo
 
IROYINO ma se o, nibi ti Johnson ti n taja loju titi l'Akure ni moto te e pa si
Surusuru lomije n da loju awon eeyan to wa nibi toko akero kan
....................................................................
Leyin ojo meta ti won ti n wa Bako n'Ilara-Mokin ni won ri oku re ninu igbo
Lowolowo ba a ti n ko iroyin yii, pelu iberu-bojo lawon eeyan ilu Ilara-Mokin
....................................................................
Friday paro pe won ja tanka epo gba lowo oun, lo ba loo ta a sona Jebba
Pelu bi ori se n ta awon omo orile-ede Naijiria fun bi epo bentiroolu se won bii imi eegun,
....................................................................
Grace atale re pa oko e n'Iyana-Ipaja
Ko seni to le so pato ohun ti Lucky Bassey, eni odun mokandinlaaadota se fun iyawo re Grace,
....................................................................
Nitori wahala ojoojumo, komisanna olopaa pase kawon Fulani ni kaadi idanimo
Komisanna olopaa nipinle Ondo, Abileko Hilda Harrison,
....................................................................
Eeyan mejila padanu emi won ninu ijamba moto n’Iseyin
Ojo buruku lojo Isegun, Tusde, ojo kejila, osu yii,
....................................................................
Iyaale ile to fi kokeeni soyun ti n ka boroboro
Owo ileese to n ri soogun oloro gbigbe lorile-ede yii,
....................................................................
Lori esun jibiti, oloye foju bale-ejo
Baba oloye kan toruko re n je Joseph Akinnawonu ati okunrin kan,
....................................................................
Mumini lu magun lara iyawo oloye ilu n’Iyana-Offa
Iku okunrin awako ero kan to n je Mumini niluu Lalupon, nipinle Oyo,
....................................................................
Owo te Wahab nibi to n ti n se'kinni' fomo odun mewaa legbee ogiri
Bi won ba n wa oniranu aye atorun, omokunrin eni ogun odun kan
........................................................................
Umaru gbe oogun wo kootu, ladajo ba da igbejo duro kia
Bii iran lawon ero kootu pelu Adajo Omolade Awope n wo olujejo kan, Ibrahim Umaru,
........................................................................
Owo ti te Segun to fole onile n'Ileefe
Ileese olopaa ipinle Osun ti da omokunrin eni odun mejidinlogun kan, Segun Micheal,
........................................................................
Awon asofin ni kijoba apapo se afara elese si Osodi-Apapa
Latari ijamba oko to n fopo emi sofo ati bi orisiirisii ajalu mi-in bee
........................................................................
Omoleye fo soobu l'Ondo, ladajo ba ran an lewon
Ojoru, Wesde, ose to koja lawon olopaa wo omokunrin kan toruko re n je Ojo Omoleye
........................................................................
Arungun loko mi, gbogbo irinse mi lo ti baje, mi o fe e mo—Abigail
"Loooto ni mo maa n mu oti, sugbon igo kan pere
........................................................................
Awon ode akoni seye ikeyin fun Asipa Ilu Oje-Owode
Tibu tooro Oke-Ogun, nipinle Oyo, lawon ode akoni atamatase ti tu yaaya jade lati seye ikeyin
........................................................................
Matthew ji ATM onibaara e l'Osogbo
Matthew Abi, omo odun mejidinlogun kan ti foju bale-ejo majisreeti ilu Osogbo
........................................................................
 
E tun le pade wa lori ero
Eyin na e so si oro yii o
Nje awon Boko Haraamu le dekun ati ma ju bombu kaakiri ile yii ?

E wo esi ibo nibi yii

                   © 2011 Ile ise Alaroye Powered by Future Global Integrated Resources Ltd.